INTRODUCTION IN ENGLISH
I am Afolayan Stephen, a 25 years old BSc. graduate in Media and communications, from Nigeria. I am a music artist, and crypto investor. I believe in this motto "what's worth doing is worth doing well".
I am well knowledged in my native language because right from when i was young my parents made sure i learnt it, and also how to write in it too. I love open-source projects because of their willingness to share ideas together, which is why i would love to translate for them.
I have done some translations on crowdin which you can find through my crowdin profile
INTRODUCTION IN YORUBA
Oruko mi ni Afolayan Stephen, mo je omo odun arundinlogbon to kawegboye BSc. Media and communications lati orile-ede Naijiria. Akorin ni mo je, ati eni to n nawo sinu crypto. Mo nigbagbo ninu gbolohun oro yi to wipe "ohunkohun ti to se ni to se Dara Dara".
Mo ni imo ninu ede abinibi mi toripe awon obi mi daju pe mo ko lati kekere, ati pelu bi wan se n ko eden naa sinu iwe. Mo nife si awon ise open-source toripe won yonda lati fi ero parapo, tori naa ni fo si fe se itumo fu n won. Mo ti se awon itumo Kan Kan Lori crowdin ti e le fi se ayewo nibi crowdin profaili
AUDIO RECORDING
https://soundcloud.com/afolayan-stephen/recording-davinci-utopian